Skip to content
Home » GOSPEL SONGS » Tope Alabi – Omo Ranti (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Omo Ranti (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Omo Ranti (MP3 Download Lyrics)
Tope Alabi – Omo Ranti (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Omo Ranti MP3 Download (Lyrics, MP4)

Omo Ranti” is a gospel song by Tope Alabi the Nigerian Gospel singer, film music composer and actress. who is also known as Ore ti o common and as Agbo Jesu from her album “Agbelebu”,

Omo Ranti” mp3 download is accessible for streaming and downloading by means of all major computerized outlets around the world.

Download Omo Ranti MP3 By Tope Alabi (Lyrics, Video)

https://youtu.be/SPFvPDdmZlg

DOWNLOAD MP3

Thanks for checking out songs on gospelcover.com , God bless you
Want the Videos & songs of other Trending Gospel Artist? Click HERE

Lyrics: Tope Alabi – Omo Ranti

Interlude
Ọmọ rántí o oo
Ọmọ ma gbàgbé ọmọ ẹnití ìwọ ń ṣe o o o o
Ìgbàlà ni eee àsìkò ìmọ̀ rẹ tidé o
Ọmọ ma gbàgbé Ẹlẹ́dà rẹ
(Ọmọ rántí)
Ọmọ rántí o oo, Ọmọ ma gbàgbé, ọmọ ẹnití ìwọ ń ṣe o o
Ìgbàlà ni eee àsìkò ìmọ̀ rẹ lèyí o
Ọmọ ma gbàgbé Ẹlẹ́dà rẹ
Má gbàgbé ẹni tó ṣẹ̀dá rẹ
Ilé ti a fi t’ọ́mọ, ìrì ni o wo o
Ọmọ tí ò lá faradà yóò san ẹ̀jẹ́ fátúnbọ̀tán
Ìgbà lọ̀dọ̀ hùn nilayé
Àgbà fẹrẹ̀ kàn ọ̀dọ́ ná o
Tara ṣàṣà ọmọ lòpin rẹ kódà
Sekíá nígbà òwúrọ̀
Ọmọ rántí o
Ọmọ ma gbàgbé, ọmọ ẹnití ìwọ ń ṣe o o
Ìgbàlà ni eee àsìkò ìmọ̀ rẹ tidé o
Ọmọ ma gbàgbé Ẹlẹ́dà rẹ
Tabá bá ọ wí to ba ń warunkì
Àwọn àgbà lọ́mọ ta ò kọ́ a gbélé takọ́ tà o
Ṣàṣà lọmọ ta ò kọ́ o, ìwọ̀n lọmọ to ń gbọ́ràn
Ọmọ ma pamí tó bá ṣe díẹ̀ yóò dọmọ má para rẹ
O ti tójúbọ́ lo ṣe yan èyí o fẹ́yàn yóyá
Bóoba rántí
Onígbá lo ń sọ’gba ẹ̀ lórúkọ
Ohun o bá pe ra rẹ
Ọmọ rántí o
Ọmọ ma gbàgbé, ọmọ ẹnití ìwọ ń ṣe o o
Ìgbàlà ni, àsìkò ìmọ̀ rẹ
Ọmọ ma gbàgbé Ẹlẹ́dà rẹ
Ọ̀pọ̀ ọmọ ti báyélọ wọn ti káṣà ìdákùdá
Ọkùnrin ò le dọ̀bálẹ̀ kágbà débi obìnrin a kúnlẹ̀ kí ẹnitójù
Ọrọ àlùfànsá lẹ́nu wọn
Àwọn ọmọ níbì míràn
Ayé ń bàjẹ̀ ẹ mámà pé o ń dára
Ọ̀gẹ̀dẹ̀ ń bàjẹ́ ẹ má sọpé o ń pọ́n
Ọmọ rántí o
Ọmọ ma gbàgbé, ọmọ ẹnití ìwọ ń ṣe o o
Ìgbàlà ni, àsìkò ìmọ̀ rẹ tidé o
Ọmọ ma gbàgbé Ẹlẹ́dà rẹ
Interlude
Suurú baba iwà o kìíṣe t’ọ̀dọ́ ìwò yí mọ́ o
Ọ̀dọ́ ayé ti tọwọ́ bọ̀bọ̀kubọ̀ àfàìtán bẹnẹ tẹ n mami bí erinmi l’ókun
Ọmọ tí o janu lẹ́nu ọmú to wa ń fẹmi famú owó, o fẹ́ di bọ̀rọ̀kiní láwùjọ
Mọ́tò àtàtà, ilé alára, góòlù iyebíye lo fẹ́rà o
Ẹmá gbàgbé àjẹ ìwẹ̀hìn tó pelédè ìjosí, ikú òjijì dẹ̀dẹ̀ lo fi mí ṣeré
Ma fẹ̀mi ẹ tọrọ fún sàtánì, jọ̀wọ́ ronú o ọmọ rántí, ọmọ ma gbàgbé Ẹlẹ́dà rẹ
(O mi pè ọ, o ń kọlẹkùn ọkàn rẹ)
Chorus: Ọmọ rántí o oo
Ọmọ ma gbàgbé ọmọ ẹnití ìwọ ń ṣe o o o o
Ìgbàlà ni eee àsìkò ìmọ̀ rẹ tidé o
Ọmọ ma gbàgbé Ẹlẹ́dà rẹ
Bẹ o ba gbọrọ òbí o, tẹ o tún gbọ́ t’Ọlọ́run
Dẹ̀dẹ̀ iku ń bẹ lóde ikú ma ń bẹ lóde
Dẹ̀dẹ̀ iku ń bẹ lóde ikú ma ń bẹ lóde o ń polówó ẹya dákun
Ẹ gbọ́rọ̀ mi, kẹya gbọ́ tèmi yùngbà yùngbà ayiyin ni
Kẹ ma pa òbí yin lẹ́kún má mà sọ wọ́n dàgàn alẹ́,
Yungba yungba ewu ò bánilára
Ò ní lè jàkàrà, ọ̀rẹ́ ko tún mu daní
Ẹsin to ko sáré ìran ni yóò wò gbẹ̀hìn
O lè rìrìn àjò kotún wà nílé o
ko ma lọ jẹ́pé ko ma lo kuku
Wá kéní kotó kéjì dandan ni àìkawé àìgbẹ́kọ̀, oféyege elere egéle alera efe
Wọn fẹ gba òkùnkùn dalágbára kòní le lọ́ra ẹ̀mi rẹ rárá
Ayòbẹ a kún ẹbí alápatà
O fẹ́ jèrè rẹ sọ́run àpádì ni rántí Ẹlẹ́dà rẹ nígbà èwe rẹ
Jésù fẹ́ràn rẹ nígbà tí ọjọ ibi kòítì dé
Ògo Ọlọ́run lo jẹ́, mámá jẹ kéṣu o yọ̀ọ́ ṣubú
F’ògo Ọlọ́run hàn lọ́nà gbogbo
Májẹ kóhun ayé tàn ọ pa o jàre
Kí lèrè Ẹlẹ́dà rẹ to ń pe ọ níle oun
Ọmọ padà bá Ẹlẹ́da rẹ làjà
To bá le yii padà ko ṣàtúnṣe ayé rẹ, ṣàṣàrò
Dẹ̀dẹ̀dẹ̀ ni yóò rọ kókò rẹ lágbàlá
O lóhun rere fún ọ nípamọ́
Ma wobi òkùnkùn to ti wọ́rìn jìnà padà o le gba o ṣe kíá
Dẹ̀dẹ̀dẹ̀ ni yóò rọ kókò rẹ lágbàlá
Ọjọ́ iwájú rẹ o mà da
Má bẹ̀rù ẹni Ọlọ́run lè pa
Ẹni to tóoni gbà ni o sa wá bá o
Dẹ̀dẹ̀dẹ̀ ni yóò rọ kókò rẹ lágbàlá
Eto to filesile fun o ju wura iyebiye lo
Jésù dúró lẹ́nu ọ̀nà o ń dúró o ń pè ọ o ọ́mọ́ wọlé wọlé wọléAlso Maverick City – King of Kings / Angels We
TRANSLATION

Interlude
Remember child
Child, do not forget the child of who you are
You are saved and your time of knowledge is here
Child do not forget your creator
(Child remember)
Child remember, do not forget, the child of who you are
You are saved and your time of knowledge is here
Child do not forget your creator
Do not forget who created you

A spoilt child destroys the home
An impatient child pays with his blood at the end of days
The youth uses his time on earth
The youth would get old soon enough
Uses your inheritance well on time
Be quick in your early years

Child remember
Child, do not forget the child of who you are
You are saved and your time of knowledge is here
Child do not forget your creator
If you are been chastised and you continue proving stubborn
The elders say an untrained child sells off ones house
Few are untrained children, few are they that listen
Child do not kill me, very soon becomes child, do not kill yourself
You are an adult that is why you have chosen your path on earth
If you remember
The time bearer names his own time
That which you name yourself

Child remember
Child do not forget the child of who you are
You are saved and your time of knowledge is here
Child do not forget your creator
So many children have gone with the world, the have taken up bad habits
A boy cannot prostrate to greet the elderly, talk less of a girl kneeling to great someone older
Bad words coming from their mouths
Children of rich pedigree
The world is getting spoilt, do not say it’s getting better
The plantain is getting spoilt do not say it is getting ripe
Child remember
Child do not forget the child of who you are
You are saved and your time of knowledge is here
Child do not forget your creator

Interlude
Patience the father of virtues doesn’t reside with our youths anymore
The youth of nowadays are involved in so much evil acts
Lovely cars, magnificent houses, expensive jewelleries are what they covet
Do not toy with sudden death
Do not sell your soul to Satan, please think, child remember, child do not forget your creator
(He is calling you, he is knocking on the door of your heart)

Chorus: Child remember
Child do not forget the child of who you are
You are saved and your time of knowledge is here
Child do not forget your creator

You should listen to your parents, and that of God
Death is close by, very close by
You should listen to my words, please listen to me
Do not make your parents cry, do not make them barren in their old age
Harm is not kind
You cannot eat your cake and have it
The horse that runs first, becomes just an onlooker afterwards
You cannot travel and also be home at the same time
So you do not die early
You are towing dangerous lanes
You want the powers of darkness, which cannot save your soul
It will take out a knife and shred you to pieces
It wants to get your soul for hell, remember your creator in the days of your youth
Jesus loves you when the evil days are not here
You are God’s glory do not let the devil make you fall
Show forth God’s glory in all ways
Do not get deceived by things of the world
What would be your creator’s gain that calls you his own?
Child reconcile with your creator
If you can turn back, to amend your ways, please think
He will make your ways easy
He has good things in store for you
Do not look how far you have gone in darkness, he can save you, come quickly
He will make your ways easy
Your future will be good
Do not fear a person that God can kill
Run to the one who is able to save
He will make your ways easy
The inheritance he kept for you is more valuable than gold
Jesus waits at the door, he is calling on you, saying child come in…

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *