Please FOLLOW & LIKE our PAGE on:  

Tope Alabi – L’oro L’ero Ati Ni’se (MP3 Download Lyrics)

0
1096
Tope Alabi – L’oro L’ero Ati Ni’se (MP3 Download Lyrics)
Tope Alabi – L’oro L’ero Ati Ni’se (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – L’oro L’ero Ati Ni’se MP3 Download (Lyrics, MP4)

L’oro L’ero Ati Ni’se” is a gospel song by Tope Alabi the Nigerian Gospel singer, film music composer and actress. who is also known as Ore ti o common and as Agbo Jesu from her album “Hymnal Volume 1”,

Thank you for reading this post, don't forget to subscribe!

L’oro L’ero Ati Ni’se” mp3 download is accessible for streaming and downloading by means of all major computerized outlets around the world.

Also Download  Steve Crown – Ayaaaa ft NAWIRAS Mass Choir (Mp3, Lyrics)

Download L’oro L’ero Ati Ni’se MP3 By Tope Alabi (Lyrics, Video)

DOWNLOAD MP3

Thanks for checking out songs on gospelcover.com , God bless you
Want the Videos & songs of other Trending Gospel Artist? Click HERE

Lyrics: Tope Alabi – L’oro L’ero Ati Ni’se

Verse 1
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

Also Download  Album: Voices of Rejoice – Lift Your Hands Up Mp3 Download (Zip files)


Chrous:
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

Verse 2
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

Verse 3
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here