Skip to content
Home » NIGERIAN SONGS » Ola Ft Adeyinka Alaseyori – Atobiju

Ola Ft Adeyinka Alaseyori – Atobiju

Ola Ft Adeyinka Alaseyori – Atobiju MP3 Download (Lyrics)

Ola Ft Adeyinka Alaseyori – Atobiju MP3 Download (Lyrics)

This song Atobiju was composed by Ola and she featured Evangelist Alaseyori and the song was consummately performed with an uncommon beauty highlighting diverse African tunes to solidify the song.

Download Atobiju By Ola Ft Adeyinka Alaseyori (MP3, Lyrics, Video)

DOWNLOAD MP3

Ola Ft Adeyinka Alaseyori – Atobiju Lyrics

Olorun wa,
Ayeraye mo gbe o ga o
Mimo mimo Atobiju
Eyin nikan l’ogo ola ye fun

Verse 1 – Ola
From the rising of the sun
Unto it’s going down
Mi o r’eni to jo o
Ti mole fi o we
Ologo ara nla, t’oni gbogbo ogo
Ashiwere wipe, Olorun k’osi
N’oje ba won so, Nitori moti mo o
Olola Ni JESU mi, ewa re k’oja oye
Baba o ni bebe, sa ma t’oju mi lo
Olorun Baba Agba Oye.

Also Download  James Wilson – Love Me Anyway (Mp3 Download, lyrics)

Chorus
Olorun wa,
Ayeraye mo gbe o ga o
Mimo mimo Atobiju
Eyin nikan l’ogo ola ye fun

Adeyinka o ya now

Verse 2 – Adeyinka Alaseyori
Iyin re o le dawo duro, lenu MI Oluwa
Iba re Akoda Aye, Aseda l’ode orun
Asaju Ogun la lo, Akehin Ogun l’oje
Paripari Ola, Alebe ilu a sasi
O da wa si,
O pa wa mo
Olore e e e
Iwonikan l’awa gbe ga
Iwonikan l’awa pe bo
From the beginning of our lives
Till this very moment
Eh Eh Eh, You’ve been faithful
Ever faithful God

Chorus Atobiju

Olorun wa,
Ayeraye mo gbe o ga o
Mimo mimo Atobiju
Eyin nikan l’ogo ola ye fun

Drums Interlude

Bridge
Call: E ba n’kira, E ba n’kira, E ba n’kira fun
Response: E ba n’kira 3x

Olori Aye gbogbo – E ba n’kira fun
T’omu riri jade ninu airi – E ba n’kira fun
Orisun Ayomi l’oje – E ba n’kira fun
O ni ole ojo merin dide Baba – Eba n’kira fun

Also Download  Hillsong Worship – Highs & Lows MP3 Download (Lyrics)

O mu omi jade lati inu apata E ba n’kira fun
O rin Lori omi, sibe ko ri – E ba. n’kira. fun
Ake to bo sinu omi, igi lofi gbe jade – E ba n’kira fun
JESU Olugbala o wo odi Jericho – E ba n’kira fun

Talaka wa Lo jeun pelu awon Oba – E ba n’kira fun
Ari na Ari Lo wa di ohun igbagbe – E ba n’kira fun
Agan ojo pipe, won di Iya olomo – E ba n’kira fun
K’osi ohun to s’oro se fun Olorun Bami – E ba n’kira fun

Ah Ah ATOBIJU
E ba n’kira fun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *