Skip to content
Home » GOSPEL SONGS » Apex Choir – Iyanu (Mp3 Download, Lyrics, MP4)

Apex Choir – Iyanu (Mp3 Download, Lyrics, MP4)

Apex Choir – Iyanu

Apex Choir – Iyanu (Mp3 Download, Lyrics, MP4)

“Iyanu” is another work of art from popular music group “Apex Choir”. The talented choir group in this track worshipped and praised God in a new dimension.

Apex Choir is a popular Nigerian Gospel group of singers and songwriters. Undoubtedly one of the best, Apex Choir has become an inspiration to millions of people across the globe. He has been able to win souls for the kingdom of God with his lifestyle and songs.

Download Apex Choir – Iyanu (Mp3, Lyrics, Video)

Download Apex Choir – Iyanu (Mp3, Lyrics, Video)

DOWNLOAD MP3

Apex Choir – Iyanu Lyrics

Iyanu ni

Iyanu, iyanu
Oh oh iyanu, iyanu
Ohun gbogbo te se fun wa
O jo wa loju
Iyanu

Iyanu, iyanu
Oh oh iyanu, iyanu
Ohun gbogbo te se fun wa
O jo wa loju
Iyanu

Awa eni a ba ti ta
A ti fi ra’tupa
A d’eni aji tina wo
Awa eni a ro pe ko le pago
A se be, a kole alarinrin
Oke agba te mu wa gun
A o le mo pe iwo lo ma
Mu wa debe l’aye n bi
Iyanu leyi se loju wa

Iyanu, iyanu
Oh oh iyanu, iyanu
Ohun gbogbo te se fun wa
O jo wa loju
Iyanu

Iyanu, iyanu
Oh oh iyanu, iyanu
Ohun gbogbo te se fun wa
O jo wa loju
Iyanu

Awa omo alaini baba
Eyi te so d’omo Oba
A dupe
Awa omo eru lasan lasan
Te gbe goke agba
Awa dupe se
Oke agba te mu wa gun
A o de le mo pe
A o debe laye
Ise owo re ni (wipe)
Owo wa to fa soke, ti araye n wo
Ise re Olorun ni
Ogo t’aye n ri t’on polongo
At’odo re lo ti wa
Ohun gbogbo te se fun wa
O jo wa loju o
Iyanu ni o, iyanu ni o

Iyanu, iyanu
Oh oh iyanu, iyanu
Ohun gbogbo te se fun wa
O jo wa loju
Iyanu

Abere ti lo k’ona okun to di
Ete egan to yi wa ka o
Iyanu lo ja si
A o tete mo wipe iji to n ja
Ibukun lo ja si
Iyanu

Abere wa ti lo k’ona okun to di
Ete egan to n korin si wa
Iyanu lo pada ja si fun wa
A o tete mo wipe gbogbo iji to n ja
Ibukun ayo lo ma ko de
O ti gbe’re wa
O ti ka wa
O kore de
Abere o!

Abere ti lo k’ona okun to di
Ete egan to yi wa ka o
Iyanu lo ja si
A o tete mo wipe iji to n ja
Ibukun lo ja si
Iyanu

Also Download  Ada Ehi – Beautiful (Mp3 Download, lyrics)

Gabreli o lo n gbere wa o
Emmanueli o o n be pelu wa
Gabreli o lo n gbere wa o
Emmanueli o o n be pelu wa
A tete ji, a bo su loke
Ise Oluwa ni
Iyanu

Gabreli o lo n gbere wa o
Emmanueli o o n be pelu wa
Gabreli o lo n gbere wa o
Emmanueli o o n be pelu wa
A tete ji, a bo su loke
Ise Oluwa ni
Iyanu

Ebenezeri wa re o (This is our Ebenezer)
Nibi te ran wa lowo de (Thus far You have helped us)
Ka’ma jo o k’ayo k’a f’ogo f’olu (Let us dance, rejoice and glorify the Lord)
Ebenezeri wa reo, e ma ma se e se (This is our Ebenezer, we give thanks)
Ki ma i se ni agbara Oluwa lo ni imo at’oye (It is not our power, the hand of the Lord helped us)
Ogo t’aiye ri t’on polongo, ire lo Baba se (The glory the world sees is by Your Hand, father)
Orin Alleluya, Hosana lo gbenu wa kan (Our mouths are filled with a Hallelujah and Hosanna)

Oh… a pa’nu po a dupe (We raise our voices to give thanks)
Oh… a korin ayo a m’ope wa (We sing for joy, bringing our thanksgiving)
Oh… a pa’nu po a dupe (We raise our voices to give thanks)
Oh… a korin ayo a m’ope wa (We sing for joy, bringing our thanksgiving)
Agbon igbe ibukun aidiye le (You have granted us uncountable blessings)
To fi fun wa, la se ndupe! (This is why we thank You)

Gabreli o lo n gbere wa o
Emmanueli o o n be pelu wa
Gabreli o lo n gbere wa o
Emmanueli o o n be pelu wa
A tete ji, a bo su loke
Ise Oluwa ni
Iyanu

Ore to Olugbala se fun wa
Oba aye o le se
Hallelujah Hosannah
Ebenezer la wa n ko
Hallelujah Hosannah
Ebenezer la wa n ko
Hallelujah Hosannah
Ebenezer la wa n ko
Hallelujah Hosannah
Ebenezer la wa n ko
Hallelujah Hosannah
Ebenezer la wa n ko

Oh oh
You are good, You are good
You are good to us
You are good, You are good
You are good to us

Ore to Olu se
Ohun lo je a dupe
Ore ojulowo
Ara me riri
Gbanko gbi ibukun
Ore yi dun yeye

Ewa bami ayo
Ewa bami ayo
Gbogbo eniyan, e ejowo
Ewa bami ayo

Ore to Olu se
Ohun lo je a dupe
Ore ojulowo
Ara me riri
Gbanko gbi ibukun
Ore yi dun yeye

A korin o a yin Baba
A korin o a yin Baba
A fi ilu didun so ore re
Ire lo l’ope Oba iye
Hallelujah ogo
A o ma yo

Also Download  Bethel Revival Choir – Mawu Akpe na Wo Mp3 Download (lyrics)

Ko su wa lati ma ko orin ti igbani
Ogo f’olorun Aleluya
A le fi igbagbo korin na s’oke kikan
Ogo f’olorun, Aleluya!

Omo olorun ni eto lati ma bu s’ayo
Pe ona yi nye wa si,
Okan wa ns’aferi Re
Nigb’o se a o de afin Oba wa ologo,
Ogo f’olorun
Ogo f’olorun
Ogo f’olorun
Aleluya!

Igba ti ba danwo
Ke me yo
Ke si gbadura
Nitori ife Re be fun wa
K’ema korin, k’ema jo
Ke si ma yo ninu ijo mimo
ife Re be fun wa

Ore to Olu se
Ohun lo je a dupe
Ore ojulowo
Ara me riri
Gbanko gbi ibukun
Ore yi dun yeye

A korin o a yin Baba
A korin o a yin Baba
A fi ilu didun so ore re
Ire lo l’ope Oba iye
Hallelujah ogo
A o ma yo

Etu yaya
Etu yaya
Etu yaya
Etu yaya
Etu yaya
Yoo j’oba
Ajoba mo
Yoo j’oba

Oluwa lo se yii o
Ki n se eniyan
Kolebaje
Oluwa lo se yii o
Ki n se eniyan
Kolebaje o

Imo kimo ko ma gbodo jo,
Ete kete koleduro o,
Enikeni to ba di eru oran
Ni o fi ara re gbe
Tori Oluwa lemi baduro

Mo ntesiwaju lona na
Mo n goke si lojoojumo
Mo gbadura bi mo n se lo
Oluwa jo gbe mi soke

Oluwa jo gbe mi soke
Fa mi lo si ibi giga
Apata to ga ju mi lo
Oluwa jo gbe mi soke

Oluwa jo gbe mi soke
Fa mi lo si ibi giga
Apata to ga ju mi lo
Oluwa jo gbe mi soke

Ko wo, ko wo
Ko wo, ko wo
Ara mo wo
Oju ti won
Oju ti baba won
Ibi aye f’oju si
Ona o gba be rara
Ah eh…

Won se ba oni mu
Won se ba oni mu
Won se bi mi oni mu
Won se bi mi oni mu se
Won se ba oni mu
Re bo wale o
Iran…a mu re bo wale

Mo tewo ayo mo gba re o
Mo tewo ayo mo gba re
Mo tewo ayo mo gba re o
Mo tewo ayo mo gba re

Mo tewo ayo mo gba re o
Mo tewo ayo mo gba re
Mo tewo ayo mo gba gbogbo mo
Mo tewo ayo mo gba re

Won se ba oni mu
Re bo wale o
Iran…a mu re bo wale

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *