Please FOLLOW & LIKE our PAGE on:  

Tope Alabi – Orun Oun Aye (MP3 Download Lyrics)

0
2164
Tope Alabi – Orun Oun Aye (MP3 Download Lyrics)
Tope Alabi – Orun Oun Aye (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Orun Oun Aye MP3 Download (Lyrics, MP4)

Orun Oun Aye” is a gospel song by Tope Alabi the Nigerian Gospel singer, film music composer and actress. who is also known as Ore ti o common and as Agbo Jesu from her album “”,

Thank you for reading this post, don't forget to subscribe!

Orun Oun Aye” mp3 download is accessible for streaming and downloading by means of all major computerized outlets around the world.

Download Orun Oun Aye MP3 By Tope Alabi (Lyrics, Video)

DOWNLOAD MP3

Thanks for checking out songs on gospelcover.com , God bless you
Want the Videos & songs of other Trending Gospel Artist? Click HERE

Lyrics: Tope Alabi – Orun Oun Aye

Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Didara orun oun so togo Re o Olorun
Ewa Re to yi aye ka n so togo Re bo ti po to
Gbogbo eda eranko at’ewebe n yin O o
Ise owo Re gbogbo lo n keyin le, won yin O o Baba
Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Ola lo wo laso, ogo lo fi pa kada orun
Ika ese Re o n han l’ori apata
Esin Re n fogo yan l’ori awo okun o Olola nla
Kini o waa se mi ti n o jokeleyo
Ti n o ni le juba Re Oba
Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Gbogbo eemi inu mi o n yin O yato Olorun mi
Iwo to mu la ina koja to fi mumi goke
Kini mba fi fun O
Kini mo tosi ninu Oreofe ti mo rigba lodo Re
Oba ye mida majemu lati nu’mole
Oro ye ye osise
Oba ti ki n dale oro Ore
Iwariri ni n o fi juba Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here