Skip to content
Home » GOSPEL SONGS » Tope Alabi – Kape Laye (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Kape Laye (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Kape Laye (MP3 Download Lyrics)
Tope Alabi – Kape Laye (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Kape Laye MP3 Download (Lyrics, MP4)

Kape Laye” is a gospel song by Tope Alabi the Nigerian Gospel singer, film music composer and actress. who is also known as Ore ti o common and as Agbo Jesu from her album “Alagbara”,

Kape Laye” mp3 download is accessible for streaming and downloading by means of all major computerized outlets around the world.

Download Kape Laye MP3 By Tope Alabi (Lyrics, Video)

https://youtu.be/gq730kpZCyQ

DOWNLOAD MP3

Thanks for checking out songs on gospelcover.com , God bless you
Want the Videos & songs of other Trending Gospel Artist? Click HERE

Also Download  Tope Alabi – Oluwa, Anu Re Duro (MP3 Download Lyrics)

Lyrics: Tope Alabi – Kape Laye

Kape laye Ka lo Ile aye titi
Ko ni Kaye gbo ooooooo
Aye lole lo niyan keee gbo
Igba ta gbe laye Ohun a gbe Ile aye she gbogbo
Keledua je kaa le pitan rere
{Edmuare Edumare, ope mi po lodo re }x
omi aye to ru siwa seyin o
{Iwo loo o je ko gbemi lo }2x
awon kan gbaye won pitan ise titi,
won pitan isoro kolopin rara,
oro won o papa jasayo o mase, ojo jo aye ni won foju sogbere eku,
titi iku fi pa won, won ko lelu dupe.
{Edmuare Edumare, ope mi po lodo re }x
omi aye to ru siwa seyin o
{Iwo loo o je ko gbemi lo }2x
Awọn kan gb’ayé wọn jadun ayé Títí won gbàgbé asèdá t’oda ayé
Ọrọ’ ayé rú bo wọn lójú jọjọ alumoni Wọn l’ayé wọn f’ogo rẹ fún satani nii
Igbagbe ṣewọn pé òun gbogbo tọwọ asèdá wa o’mase o’mase
{Edmuare Edumare, ope mi po lodo re }x
omi aye to ru siwa seyin o
{Iwo loo o je ko gbemi lo }2x

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *