Please FOLLOW & LIKE our PAGE on:  

Tope Alabi – Oorun Oun Aye (MP3 Download Lyrics)

0
1117
Tope Alabi – Oorun Oun Aye (MP3 Download Lyrics)
Tope Alabi – Oorun Oun Aye (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Oorun Oun Aye MP3 Download (Lyrics, MP4)

Oorun Oun Aye” is a gospel song by Tope Alabi the Nigerian Gospel singer, film music composer and actress. who is also known as Ore ti o common and as Agbo Jesu from her album “Agbelebu”,

Oorun Oun Aye” mp3 download is accessible for streaming and downloading by means of all major computerized outlets around the world.

Download Oorun Oun Aye MP3 By Tope Alabi (Lyrics, Video)

DOWNLOAD MP3

Thanks for checking out songs on gospelcover.com , God bless you
Want the Videos & songs of other Trending Gospel Artist? Click HERE

Lyrics: Tope Alabi – Oorun Oun Aye

Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo n kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Orun oun aye kun fun ogo Re

Egbegberun awon irawo n kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Didara orun, o n so togo Re o Olorun

Orun oun aye kun fun ogo Re

Ewa Re to yi aye ka, n so togo Re o bo ti po to

Gbogbo eda, eranko at’ewebe n yin O o
Ise owo Re gbogbo loke nile, won n yin O o Baba
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re

Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Ola lo wo laso, ogo lo fi pa kaja orun
Ipa ese Re, o n han l’ori apata
Esin Re n fogo yan, l’ori awon okun o Olola nla
Kini yo waa se mi, ti n o j’okele yo, ti n o ni le juba Re Oba

Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Gbogbo eemi inu mi, o n yin O yato o, Olorun mi

Iwo to mu mi la ina koja, to fi mumi goke, kini mba fi fun O
Kini mo to si ninu oore ofe ti mo ri gba lodo Re
O ba aye mi da majemu lati ‘nu ole
Oro Re ye, o si se
Oba ti ki i dale oro Re
Iwariri ni n o ma fi juba Re o
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here