Skip to content
Home » GOSPEL SONGS » Tope Alabi – Lae La O Ma Bo Oluwa (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Lae La O Ma Bo Oluwa (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Lae La O Ma Bo Oluwa (MP3 Download Lyrics)
Tope Alabi – Lae La O Ma Bo Oluwa (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Lae La O Ma Bo Oluwa MP3 Download (Lyrics, MP4)

Lae La O Ma Bo Oluwa” is a gospel song by Tope Alabi the Nigerian Gospel singer, film music composer and actress. who is also known as Ore ti o common and as Agbo Jesu from her album “Hymnal Volume 1”,

Lae La O Ma Bo Oluwa” mp3 download is accessible for streaming and downloading by means of all major computerized outlets around the world.

Download Lae La O Ma Bo Oluwa MP3 By Tope Alabi (Lyrics, Video)

https://youtu.be/JeM_-ediQp0

DOWNLOAD MP3

Thanks for checking out songs on gospelcover.com , God bless you
Want the Videos & songs of other Trending Gospel Artist? Click HERE

Also Download  Tope Alabi – Ibinu Sinmi Laya Were (MP3 Download Lyrics)

Lyrics: Tope Alabi – Lae La O Ma Bo Oluwa

[Verse 1]
Nitori iwo je oluwa, lae la oma bo o
Nitori iwo ni oluwa, lae la oma bo o
A o pelu a o pelu a o pelu angeli bo o
A o pelu a o pelu a o pelu awon eniyan bo o


[Chrous]
A o pelu a o pelu a o pelu angeli bo o
A o pelu a o pelu a o pelu awon eniyan bo o

[Verse 2]
Ogangan oju awon angeli, lae la oma bo o
Imole tomo orun ja aye, lae la oma bo o
Ogunwa ninu imole ara re, lae la oma bo o
Akoso aye ateda gbogbo, lae la oma bo o
Imole re oluwa duro lailai, lae la oma bo o

[Verse 3]
Oju ogo re nko monomono, lae la oma bo o
Imole orun dan itanshan, lae la oma bo o
Si iwo ti oruko re yio wa titi lai, lae la oma bo o
Ogo re titi de opin imole orun, lae la oma bo o
Ogo toji oku ojo kerin dide o, lae la oma bo o

[Verse 4]
Si iwo eni mimo israeli, lae la oma bo o
Si iwo ti yio ku nigbati aye batan, lae la oma bo o
Ibujoko eniti idajo gbogbo wa, lae la oma bo o
Ogo t’awon ti ara pada yio ri lojukoju, lae la oma bo o
Si iwo ogo ibere ti o lopin, lae la oma bo o

[Ref]
Lae la o ma bo o, lae la o ma gbe o ga
Lae la o ma bo o, kabiesi o oba
Lae la o ma bo o, lae la o ma gbe o ga
Lae la o ma bo o, kabiesi o oba

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *