Skip to content
Home » GOSPEL SONGS » Tope Alabi – Abo Mi Kodara (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Abo Mi Kodara (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Abo Mi Kodara (MP3 Download Lyrics)
Tope Alabi – Abo Mi Kodara (MP3 Download Lyrics)

Tope Alabi – Abo Mi Kodara MP3 Download (Lyrics, MP4)

Abo Mi Kodara” is a gospel song by Tope Alabi the Nigerian Gospel singer, film music composer and actress. who is also known as Ore ti o common and as Agbo Jesu from her album “Alagbara”,

Abo Mi Kodara” mp3 download is accessible for streaming and downloading by means of all major computerized outlets around the world.

Download Abo Mi KodaraMP3 By Tope Alabi (Lyrics, Video)

DOWNLOAD MP3

Thanks for checking out songs on gospelcover.com , God bless you
Want the Videos & songs of other Trending Gospel Artist? Click HERE

Lyrics: Tope Alabi – Abo Mi Kodara

Okunrin a fabo sile
Obinrin roja, a padabo
Egbe eni rajo gbogbo
Se ni won n fabo sile o
Ori mi jowo
Eda mi jowo
Bimo ba roja
Tojo terun

Abo mi kodara

Okunrin a fabo sile
Obinrin roja, a padabo
Egbe eni rajo dele
Se ni won n fabo sile o
Ori mi jowo
Eda mi jowo
Bimo ba roja
Tojo terun
Abo mi kodara

Aseda to da aye o
O da ohun gbogbo sile aye
O wa da eniyan laworan arare
O fi wa joba Lori won
O da wa sile aiye
Lati wa joro ohun gbogbo to da
Aye lo fi se oja
Sewa ri orun ile wa ni

Okunrin a fabo sile
Obinrin roja, a padabo
Egbe eni rajo de
Se ni won n fabo sile o
Ori mi jowo
Eda mi jowo
Bimo ba roja
Tojo terun
Abo mi kodara

Aaa aye a da bi oja
Ta mi na laiye
T’Olukuluku n na ja re
Ti yo fi pada sile
Eni lowuro
A so owuro
E ni losan ko ni dale

Oloja ale a na tire
Gbogbo eniyan ni yo rele
Sugbon bo ti wu koja peto
Keni to n naja peto
Eda e ma je a gbagbe rara
Ile labo isinmi oko

Ori mi jowo
Eda mi jowo
Bimo ba roja
Tojo terun
Abo mi kodara

Eni to ran wa
A o jiyin fun
Eda e ma je a gbagbe rara
Bo binrin ti gbowo obe roja
La o se jise
On rode wa n reti abo wa
E ma je a tajo gbe sajo

Ori mi jowo
Eda mi jowo
Bimo ba roja
Tojo terun
Abo mi kodara

Ewu igbeyin de tan ara mi
Aye ti n sori kodo
Iku n be lode
Arun n polowo
Bawo nimura sile re
Ijamba n se lorisirisi
E o tete ma a fura
Ore mi ma gbagbe ile
Hun Hun

Eni to da wa ma fewa
O fewa
Ko fese buburu
O ti silekun ona tooro
Jankariwo eru ko nile gbabe
Bi ole
Bi agbere
Ipaniyan n ko
Iro pipa
Eke inunibini

Iborisa pelu Osho
Awon iye ni Jankariwo
Onidikudi o ni koja
Oya tete yese owo re wo
Ko lojo tode
Ona tooro
Ko gbelese
Keya tete gbo seti
Anaja ma gbagbe ile
Hun hun

Okunrin a fabo sile
Obinrin roja, a padabo
Egbe eni rajo gbogbo
Se ni won n fabo sile o
Ori mi jowo
Eda mi jowo
Bimo ba roja
Tojo terun
Abo mi kodara
Jo o jo o, aabo mi kodara

Mura lati fabo sile
Bobinrin tiroja obe bo
Mura lati pade oba
Ajo o nidun
Ko nile ma rele
Opo eda ti gbadun oja
Adarihurun won saye
Dawa i lo
Ko ni pe e tan oo
Odun aye

Igba to ba ti nigba
O ti ni opin
Egberun odun a toope
Ore mi
Ijafara lewu
O ti fi Jesu yii
Solu gbala
Eni ba gbaa gbo
Yo ri iye
E ni ba gbaa gbo

Yo ri iye
Fa aye e fun
Iku ati Iye
Iseju kan lo la won
Iseju tokan
Ko seni tomo
Ona to toka sona iye
Jesu oluwa lona naa
Ona to toka sona iye
Igbala Miran

Ko si ara mi
To tun ju Jesu
To ku Lori igi
Oko egbe
Ade egun
Oti kikan
Iya to je Lori wa
Igbala n kigbe
Wa gba a o
Iku Jesu

Tori gbogbo wa ni
Igbala re oo
Ona iye
Eni ba gbaa gbo
Yo ri iye
Fa aye e fun
Iku ati Iye
Iseju kan lo la won
Iseju tokan
Ko seni tomo

Ona to toka sona iye
Jesu Oluwa lona naa
Ona to toka sona iye
Igbala n ki gbe
Wa gba ooo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *