Please FOLLOW & LIKE our PAGE on:  

Lyrics Tope Alabi – Oba Aseda

0
1171
Lyrics Tope Alabi – Oba Aseda

Lyrics Oba Aseda By Tope Alabi

A toto n to Olodumare, Olorun ogo,
Iba Re, Iba o, Akoda aye, Iwo nikan lo to, iba!
A de’da, a m’eda Oba
Alamo to mo ‘ponri eda o

Thank you for reading this post, don't forget to subscribe!

Akoko orun on aye
Opo kan a gbamu aye o
Ogo ni mo wa yin o o Oba
Kabiyesi Re, Olorun toto
Ogo, yeeee, ogo
Akoko ade Iwo loba
Omimi aye ti o le mi lailai o
Olu inu awon orun
Asaya apesin asako
Iwo to tobi ju o lorun
O f’aye s’apoti itise lasan
Ogo, yeeee, ogo
Ogo ye o, yeeeee ogo

Olorun agbaye, mo f’ogo fun O ooo
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Iwo lajulo ti o see julo, mo f’ogo fun O Baba
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Atetekose Adiitu Oro, mo f’ogo fun O Baba
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Alapanla to so’le aye ro, mo f’ogo fun O ooo
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Iwo ni ‘gunwa ogo ti o lafiwe, mo f’ogo fun O Oba nla
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Awari Re aimo ni f’aye at’orun

Also Download  Tope Alabi – Sami Iyin (Mp3 Download, Lyrics)

Ipa o to ju gbogbo ipa lo
Angeli o le s’akawe ogo Re
Didan ninu ewa at’orun d’orun
O da’ye k’ohunkohun to d’aye
Akoko k’angeli orun to wa
Iwo to n s’ohun to tobi ju awari lo
Owo ogo to f’ara s’ohun gbogbo logo
Ogo yeeeee ogo
Iba o, yeeeee iba o
Iba Re Olorun o, Oba ayeraye e
Kabiyesi Re o, Iwo nikan lola ododo to si
Mo wa juba Re o, Iwo nikan lola ododo to si o

Click HERE For More Lyrics

Olorun agbaye, mo f’ogo fun O ooo
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Erujeje Arugbo Ojo, Agba lailai on lo je
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Olurapada wa, Ododo to n tan ‘mole
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Oba t’aa bi, sugbon ti a ko da
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Ilekun to ti mo iku, Kokoro si iye ayeraye
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
You are the Might above all mights

Angels count Your glory, incomparable
Shining in beauty from heaven to heaven, Creator of eternal things
You are the first, before the heavenly angels
You bigger than searchable
Glorious and stylishly working all glory
Glory Oh Glory (Ogo ogo)
Unquestionable Great King, be Thou glorified Daddy
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Awon angeli juba Re, lojoojo o lorun
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Embodiment of wisdom and power You are
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Agbaagba lorun juba Re, won fi’ba yi O ka Baba
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O

Also Download  Tope Alabi Ft. TY Bello – All The Glory (MP3 Download Lyrics)

Worker of numerous wonders, worshipped in trembling
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Gbogbo aye mi ni mo fi juba Re, gba ogo lori mi o Baba
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
You are the King Creator, be Thou glorified
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Ola ododo lo to si ‘Wo nikan nikan o
Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O
Iba Re Olorun o, Oba ayeraye e
Kabiyesi Re o, Iwo nikan lola ododo to si
Mo wa juba Re o, Iwo nikan lola ododo to si o

Thanks for checking out Lyrics on Gospelcover.com, God bless you
Want the Lyrics of other Trending songs? Click HERE

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here